Take a fresh look at your lifestyle.

Àsọyépọ̀ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Pẹ̀lú Orílẹ̀-èdè Faransé Lórí Ètò Ọ̀gbìn, Eré Ìdárayá Àti Ẹ̀kọ́

167

Àgbáríjọpọ̀ àwọn Gómìnà lábẹ́ ìdarí alága àjọ Nigeria Governors’ Forum, (NGF) Gómìnà Abdulrahman AbdulRazaq ti ìpínlẹ̀ Kwara ti ni àjosọyépọ̀ pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ láti ilẹ̀ Faransé ti wọn sì jọ ní àfojúsùn kan náà lórí àwọn nǹkan tó ṣe gbógì ti orílẹ̀-èdè méjéèjì ń fẹ́ tó ṣe pàtàkì jùlọ.

Alága àwọn àjọ NHF sọ pé, ètò náà ti mú kí ọ̀pọlọpọ̀ ilé iṣẹ àti àwọn to ṣẹṣẹ bẹrẹ láti parapọ̀ kí wọn sì jọ lẹ̀pọ̀ ki ìtèsíwájú leè wà láàrin àwọn ilé iṣẹ́ Nàìjíríà àti àwọn ti ilẹ̀ Faransé.

Ó tún sọ pé, ìbáṣepọ̀ náà yóò jẹ kí ifọrọwọrọ tó ti wá nípa àkànṣe iṣẹ ní ipinlẹ Kwara, pàápàá jùlọ ní ti ilé iṣẹ, èyí to jọ mọ́ ètò ọ̀gbìn tó ń po àwọn nǹkan papọ̀ abbl..

Gómìnà AbdulRazaq sàlàyé síwájú pé, ìfọ̀rọ̀wérọ̀ náà jẹ ìtèsíwájú sì ti Ìrìn-àjò ààrẹ wà sí orílẹ̀-èdè Faranse nigba ti ààrẹ ń fẹ́ àtìlẹ́yìn àgbáyé fún ìtesiwaju ọrọ̀ ajé.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Comments are closed.

button