Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ Ìlera Lágbayé Ṣe Ẹ̀tọ̀ Ìlànà Ọ̀nà Àbayọ Fún Àìsàn Ìgbóná.

90

Àjọ elẹ́tọ̀ àgbáyé fún ìlera (WHO) ti ṣe àwọn ètò àti ìlànà fún ọnà àbayọ lórí àìsàn Ìgbóná àkókó irú rẹ.

Wọn ní ìtọ́jú lásìkò, gbaradi lásìkò, ṣiṣe àkíyèsí lásìkò àti ìtọjú to péye láti ọ̀dọ̀ àwọn Akosemósè yóò mú kí àìsàn náà di ohun igbagbe.

Nínú àtẹ̀jáde kan láti odò àjọ àgbáyé wọn  ní àwọn ilana yìí jẹ akojọpọ íwáàdí nípa àìsàn náà èyí tí yóò sí wúlò fún àwọn ènìyàn lágbayé.

Bákanáà ni won sàlàyé bí àìsàn náà ṣe mú ìjàmbá ba àwọn ènìyàn láti ọdún 2019 Títí di àsìkò yìí.

Dọ́kítà Tedros Ghereyesus tó jẹ adari àgbà pátápátá fún àjọ WHO sàlàyé wí pé àìsàn náà jẹ èyí to buru jù to sí n gbà emi lára àwọn ènìyàn kódà o n fi àwọn ẹlòmíràn sí ipò aláàbò ará.

Ètò Ilana yìí jẹ àkọ́kọ́ iru rẹ tí àjọ àgbáyé yóò ṣe fún àwọn ènìyàn lágbayé.

Comments are closed.

button