Take a fresh look at your lifestyle.

Ìlera Ọpọlọ: Ìjọba ìpínlẹ̀ Kaduna Ṣe Àtúnṣe Àwọn Ilé ìwòsan ìjọba Tọ Le Ni Márùndinotalenigba.

107

Nínú èròngbà láti ṣe àtúnṣe àwọn ilé ìwòsan ìjọba káàkiri ìpínlẹ̀ Kaduna, ìjọba ìpínlẹ̀ Kaduna ti ṣe àtúnṣe àwọn ilé ìwòsan márùndinotalenigba. Ìdàgbàsókè ọtún

Èyí di ṣiṣe láti mú ìdàgbàsókè ba ètò ìlera ni ìpínlẹ̀.

Níbi ifọrọwọrọ pẹlú àwọn Oníròyìn ni gbọgán Sir Kashim Ibrahim ni Umma Ahmad tó jẹ Kọmísọ́nà fún ètò ìlera ló sọ èyí di mímọ̀ wí pé èyí jẹ lára èròngbà Gómìnà Iná Sani .

Ahmad sàlàyé wí pé Gómìnà ko fi ètò ìlera ṣe ere rárá,

Ó ni owó ti Gómìnà ti na lórí ètò ìlera ko kere rárá, ko da Gómìnà ti buwolu gbígbà àwọn òṣìṣẹ́ ìlera míràn láti mú ìdàgbàsókè ba ètò ìlera.

Comments are closed.

button