Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Ìbílẹ̀ Igbo-Etiti Ni Ìpínlẹ̀ Enugu Ti Bèrè Ètò Ìtọ̀jú Ọfẹ Nípa Ìlera Fún Àwọn Arúgbó.

81

Alága ìjọba ìbílẹ̀ Igbo-Etiti ni ìjọba ìpínlẹ̀ Enugu, Dọ́kítà Eric Odo sọ wí pé àwọn ti bere ètò ìtọ́jú ìlera ọfẹ fún àwọn arúgbó àti àwọn abiru.

Odo tó jẹ Oníṣègùn òyìnbó darapọ̀ mọ́ àwọn Oníṣègùn òyìnbó tókun láti ṣe ètò ìtọ́jú ofe náà.

Ó ní àwọn ti ṣe ìtọjú àwọn ènìyàn lọpọlọpọ tí àwọn opó tí yóò ma gba owó oṣù ti to ẹgbẹrun kan.

Ó ní labẹ ìjọba ìbílẹ̀ Igbo-Etiti òun fẹ́ ko jẹ èyí tí yóò ṣe mú yan gan jùlọ àti èyí tí o fi àye dé àwọn ènìyàn lọrùn.

Comments are closed.

button