Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ Àwọn Oníṣègùn Nípa Ẹyìn Àti Ìlera Ṣe Ayẹyẹ Fún Àwọn Oníṣègùn Òyìnbó Mẹ́ẹ̀dógún Ni Fásítì Igbinedion.

112

Ẹgbẹ́ Oníṣègùn àti ìtójú ẹyìn ni Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (MDCN) ni ọjọ̀bọ̀ ṣe ayẹyẹ fún àwọn Oníṣègùn òyìnbó tuntun mẹẹdogun tí wọn kose Mósè ní Fásítì Igbinedion.

Eléyìí jẹ ayẹyẹ Eleekeji iru rẹ tí yi yóò wáyé, ni ile ẹ̀kọ́ gíga náà alakọkọ wáyé ni oṣù keewa ọdún 2024.

Ọmowé Lawrence Ezemonye ti o jẹ igbákejì ilé ẹ̀kó náà sọ pàtàkì eko àti kí ènìyàn kọ́sẹ́mosẹ́.

Ezemonye ti ó sojú ọgá àgbà pátápátá fún ilẹ ìwé gíga náà, wa rọ àwọn Oníṣègùn òyìnbó tuntun náà, láti mase gbagbé ohun gbogbo ti won kò àti láti máṣe kọ̀ ọnà láti Gba emi là sílè.

Dọ́kítà Fatima Kyari tó búra fún wọn, o be wọn láti ni èkó,ifarada,amumora,àti kí wọn mase ṣe iṣẹ naa ni ọna ti ko tó.

Ó wa rọ àwọn òbí láti rí daju wí pé wọn àtìlẹ́yìn nlá fún àwọn dókítà tuntun náà

Comments are closed.

button