Take a fresh look at your lifestyle.

Bukavu: Elétò Ààbò Tó Lè Nígba Darapọ̀ Mọ́ Ikọ̀ M23

206

 

Ó ti lé Nígba àwọn Ọlópàá àti Sójà tó ti lọ darapọ̀ mọ́ ikọ̀ Alliance Fleuve Congo (AFC/M23), ikọ̀ ọlọ̀tẹ̀ ní ìlà oòrùn orílẹ̀-èdè náà – orílẹ̀-èdè olómìnira ilẹ̀ Congo.

Ayẹyẹ ìdarapọ̀ náà wáyé ní iwájú Gbọ̀ngàn adarí Ilé Iṣẹ́ olópàá, tó mú kí ọpọ̀ èrò láti ìbílẹ̀ péjo.
Èyí ríbẹ̀ látàrí àìsí ohun èèlò pẹ̀lú àyíká tó mẹ́he fún àwon elétò ààbò, bí Kọmísọ́nà olópàá àpapọ̀ ti ilẹ̀ Congo-Congolese National Police (PNC),Ọ̀gbẹ́ni Jackson Nkamba ṣe sọ.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

 

Comments are closed.

button