Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Ogun: Igbákejì Shettima Sí Ilé Ìtajà Tuntun Fún Àwọn Ọlọ́jà

289

Igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Kashim Shettima tí ṣe ìfilọ́lẹ̀ àti àti sí sí ilé ìtàjà tuntun tó wa Asero ni ìlú Abeokuta ti  wọn ti tàn Adire , ilé ìtàjà to jẹ ọgọrùn méjì ìbùsọ̀ fún àwọn ènìyàn.

Wọn ni àwọn Olùtajà yóò jẹ ànfààní ọdún kan Lai san owó, lẹ́yìn ọdún kan wọn yóò san owó tí kò ga ni lára.

Igbákejì Ààrẹ ni Lára ileri àti atilẹyin Ààrẹ Tinubu rẹ láti ṣe iranlọwọ fún àwọn olójà káàkiri.

Ọjọ́ ìṣẹgun ni igbakeji Ààrẹ sọ èyí di mímọ nígbà tí o n sí ilé taja náà ni ìlú Abeokuta.

O ní pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ àwọn ilé ìtàjà káàkiri ni àwọn ìpínlẹ̀ àtúnṣe àti ìdàgbàsókè yóò bá ètò ọ̀rọ̀ ajé wa.

Igbákejì Ààrẹ wa gbóríyìn fún Gómìnà ìpínlẹ̀ Ogun, fún àtìlẹ́yìn rẹ láti rí wí pé àwọn ènìyàn ìlú náà rí ti aje jeun

Comments are closed.

button