Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Niger Mú  Àtúnṣe Àti Ìdàgbàsókè Bá Àwọn Ilé Ìwòsàn Káàkiri Àwọn Ijọba Ìbílẹ̀ Náà 

194

Nínú èròngbà láti mú ìdàgbàsókè bá ètò ìlera káàkiri ìjoba ìbílẹ̀ márùn-únlélógún tó wà ní ìpínlẹ̀ Niger.

Gómìnà ìpínlẹ̀ náà ti bẹrẹ àwọn àtúnṣe nlá sí àwọn ilé ìwòsàn to wa láwọn ìjọba ìbílẹ̀ náà fún ìdàgbàsókè tó péye.

Ìyàwó Gómìnà ìpínlẹ̀ náà, Hajiyan Fatima Umar Mohammed Bago, to ṣáájú Ètò náà ni Minna.

Ó fi idunnu re hàn bi ìyípadà àti ìlọsíwájú ṣe ba àwọn ilé ìwòsàn ìjọba ìbílẹ̀ ati bi awọn òṣìṣẹ́ ṣe n ṣiṣe wọn.

Ìyàwó Gómìnà tun wa pé àwọn obi, pàápàá jùlọ àwọn Obìnrin láti má jáde gbà abẹrẹ ajẹsara fun àwọn ọmọ wọn.

Bákanáà lo sọ àwọn ohun èlò ìlera ti wọn Pin èyí tó jẹ ìwúlò fún àwọn ènìyàn ní agbègbè náà.

Kọmísọ́nà fún ètò ìlera ni ìpínlẹ̀ náà Dọ́kítà Ibrahim Dangana, sàlàyé wí pé ètò náà wà fún atilẹyin ìjọba Gómìnà Umar Mohammed Bago

Comments are closed.

button