Take a fresh look at your lifestyle.

Dọ́kítà Tó N Gbé Orílẹ̀-èdè US Fún Ilé Ìwòsàn Ijoba ABUTH Ni Malumfashi Ni Masini Àyẹ̀wò 

150

Dọ́kítà Titus Okunlola,tí o fi Orílẹ̀-èdè USA ṣe ibùgbé tí pàṣẹ Masini Àyẹ̀wò fún ilé ìwòsàn ijoba Ahmadu Bello (ABUTH)ni Malumfashi, ni ìpínlẹ̀ Katsina.

Àwọn alákòóso ilé ìwòsàn náà ló jẹ kí èyí di mímọ, láti ẹnu ọrẹ pàtàkì rẹ Muhammad Amoni ni ọjọ́ àìkú nigba ti wọn n ṣe àfihàn ẹrọ náà.

Ìròyìn fi dá wa lójú wí pé Okunlola tí ṣe iru èyí rí nígbà tí o jẹ akékòó ni ọdún 1978

Comments are closed.

button