Take a fresh look at your lifestyle.

Ọ̀gá Àgbà pátápátá Fún i NPHCDA Ti Pé Fun Akiyesi Pàtàkì Lori Àìsàn Ọpọlọ.

97

Ọ̀gá àgbà pátápátá fún àwọn ilé ìwòsàn ìjọba,  Dọ́kítà Muyi Aina ti rọ àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ní àkíyèsí pàtàkì nipa àìsàn tí o n ba ọpọlọ já tí wọn n pé ni Meningitis.

Ó ní nípa ṣíṣe àkíyèsí yìí ni àsìkò yóò mú kí ìtọjú wà, a sì mú kí ìtọjú wà fún oni tòhún.

Nínú ìfòròwánilénuwò pẹ̀lú àwọn oníròyìn ní ọjọ́ ajé ni ìlú Abuja ni ọ̀rọ̀ náà ti jáde láti enu ọ̀gá àgbà naa

Ó sàlàyé wí pé àisìán yìí yàrá láti se iku ènìyàn.

Ó wà ró àwọn ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti tètè ni àkíyèsí àìsàn yìí ní agbègbè owọn fún ìtọjú tó péye.

Ó ní nípa abẹ́rẹ́ àjẹsára ati àkíyèsí lásìkò yóò mú kí àwọn ènìyàn Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà bọ́ lọ́wọ́ àìsàn náà.

Gẹ́gẹ́ bí àjọ àgbáyé fún ètò ìlera ṣe sọrọ nipa àìsàn náà wọn ni ,ayi ma gbà abẹrẹ ajẹsara pé fún ọmọ náà jẹ ọkan lára àkóbá nla fún àìsàn náà

Comments are closed.

button