Gómìnà ìpínlẹ̀ Yobe, Mai Mala Buni tí fowo sí gbígbà awọn ọde tó le ni ẹgbẹrun kan láti má sọ àwọn ilé ìwòsàn ijoba to wa ni ìpínlẹ̀ náà
Dọ́kítà Babagana Tijjani to jẹ Akọ̀wé fún àwọn ilé ìwòsàn ijoba, gbe Òsùbà o Káre fún Gómìnà fún anfààní náà
Ó wa ró àwọn ènìyàn nínú ìlú láti rí wí pé anfààní nla rẹ láti kọ pa nínú ètò ààbò ìlú
O ní eléyìn yóò mú kí ọ̀rọ̀ ètò ààbò wa nínú ifọkansi, ati ki ifọkanbalẹ ba lè bá àwọn ilé ìwòsàn wa kaakiri