Take a fresh look at your lifestyle.

Àyájọ́ Àisìán Wárápá: Àjọ Ìlera Lágbayé Ṣe Àtìlẹ́yìn Láti Jẹ Kí Àwọn Ènìyàn Ni Ìmòye Nípa Àìsàn Naa.

276

Ni igbiyanju lati dẹkùn àìsàn wárápá àjọ àgbáyé fún ìlera bo síta fún ìkéde ìmòye lórí àìsàn náà fún ọdún 2024

Àkọlé ti ọdún yìí ni Àìsàn wárápá imọlẹ fún ìmòye lórí rẹ.

Àjọ ìlera àgbáyé n gbìyànjú láti rí wí pé àwọn ènìyàn ni ìmòye lórí àìsàn wárápá wọn nítorí  ẹnikẹni ba ni àisàn náà ni agbègbè wọn.

Wọn ṣe ìpolongo yìí nínú ayelujara, ìdánilékòó ati bẹẹ bẹẹ lọ.

Wọn ni àyẹwò lásìkò náà yóò ṣe iṣé ribiribi láti dènà àìsàn náà.

Wọn ni àwọn n ṣe ètò láti rí wí pé gbogbo àwọn tó ní àìsàn náà ni o gba ìtọjú tó péye

Comments are closed.

button