Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ CADEF Pe Fún Ìdíwó Lórí Ríra  Ounjẹ Lọ́jà

167

Ẹgbẹ́ tó n mójú tó ọ̀rọ̀ àwọn káràkátà (CADEF) ti tẹnumọ́ wí pé kí a wọ ṣe fun ara wa nípa ìdíwó lórí ọja oúnjẹ.

Ẹgbẹ́ yìí sọ èyí di mímọ nínú atejade kan láti ọwọ́ adari ẹgbẹ́ náà ọ̀mọ̀wé Chiso Okafkor ni ọjọ́ ìṣẹgun ni ilu Eko.

Ìpàdé yìí ni àwon ila mẹ́fẹ̀fà Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà péjú sí, ti wọn sì jíròrò lórí ọwọn gógó Iṣu, Gàrí, Ìresì, Ẹwà, Àgbàdo,epo, ẹpa, Adiye èyí tí o gbé ọwọ lórí láti inú oṣù kọkànlá sí oṣù Kejìlá odun 2023 titi sá ati àkókò yíì.

Okafor ni o ṣe pàtàkì láti ṣe ìwádìí ohun tó ṣe okun fa ati ona abayọ lásìkò.

Wọn ni pẹlu àwọn Ìwádìí lodo àwọn onimọ nipa káràkátà ohun tó lè fà ni owó okò tí wọn fi gbé dé nibi ìtajà, wọn ni  ṣugbọn ki wọn síjú àànu won àwọn ènìyàn pẹ̀lú.

Comments are closed.

button