Take a fresh look at your lifestyle.

Àdìkù ìbò bẹ̀rẹ̀ ní ìlú Eko

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

154

Ìdìbò ti bẹ̀rẹ̀ níbi àdìkù ìbò ọjọ́ Àbámẹ́ta fún agbègbè àkọ́kọ́ ní ìpínlẹ̀ Eko.

Oludije mejila ni o n dupo lati rọpo adari ile igbimọ aṣoju Naijiria tẹlẹ, Fẹmi Gbajabiamila.

Ipo Gbajabiamila ni ile igbimọ ṣi silẹ nigba ti aarẹ Bọla Ahmed yan bii Ọga agba fun awọn oṣiṣẹ rẹ.

Igbimọ olominira to n mojuto eto idibo ni Naijiria, INEC n ṣeto irọpo ibo naa ni ipinlẹ mẹrindin-lọgbọn jakejado orilẹ-ede.

 

Comments are closed.

button