Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ KADCHMA  Yóò Pèsè  Ètò Ìtọ́jú Òfé Fún Àwọn Tó kò Ni Agbára To Ni Ìpínlẹ̀ Kaduna.

173

Àjọ tó ń ṣe akojọpọ nipa ètò ìlera ní ìpínlẹ̀ Kaduna (KADCHMA) Pẹ̀lú ìbáṣepọ̀ Clinton Health Access ni àwọn yóò pèsè ètò ìtọ́jú ìlera ọ̀fẹ́ fún àwọn ti kọ ni lágbára tó láti ṣe ìtọ́jú ará wọn nipasẹ owó , láàrin ìpínlẹ̀ náà.

Wọn awọn ènìyàn tó tó ẹgbẹ̀rún lọnà Merinlelogun.

Ẹnu Mallam Abubakar Hassan to jẹ Adarí àgbà pátápátá fún àjọ KADCHMA lo sọ èyí di mímọ̀ nígbà tí o n pin ìwé ọfẹ ati ìtọjú ọ̀fẹ́ fún àwọn ọmọ ilé èkó LEA Kallon Kure, Samarin Zaria ni Ọjọ́bọ̀.

Ìpàdé yìí ní ó wa láti ọfisi olùdámọ̀ràn pàtàkì sí igbakeji Gómìnà lórí ọ̀rọ̀ ilé iṣé Aláàdáni.

Ó wa rọ àwọn ènìyàn ìpínlẹ̀ náà láti tètè lo ànfààní náà dáradára fún ìtura láàrin ará wọn.

Ó ní yóò tún jẹ ànfààní láti di owó sisan kún lórí ètò ìlera.

O gbà àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Làmọ̀ràn láti lò ìwé náà ni ona tó dára nitori o jẹ ìrànlọ́wọ́ fún àwọn òbí wọn.

Bákanáà ọ̀rọ̀ idanilẹkọ lórí ètò ìlera ko gbẹyin àti àyẹwò ọfẹ

Comments are closed.

button