Take a fresh look at your lifestyle.

Amẹ́ríkà fi mẹ́tàlá kún ilé iṣẹ́ China tí wọn kò tíì fìdí òtítọ́ rẹ̀ múlẹ̀

Eyitayó Fauziat Oyetunji

201

Amẹ́ríkà fi mẹ́tàlá kún ilé iṣẹ́ China tí àwọn òṣìṣẹ́ Amẹ́ríkà kò tíì ṣàyẹ̀wò rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí àkíyèsí ìjọba.

Labẹ ilana imuṣẹ lasiko iṣejọba Biden, ti ijọba ko ba fun awọn oṣiṣẹ Amẹrika lanfaani lati ṣe ayẹwo ibudo awọn ile-iṣẹ ti o wa lara awọn ti wọn ko ti fidi otitọ wọn mulẹ, Washington yoo wa bẹrẹ igbesẹ lati ka mọ ara awọn ti ko ni ẹtọ si eto ọja inu ilu lẹyin ọgọta ọjọ.

Ara awọn ti wọn fi kun un ni PNC Systems Co Ltd ti Jiangsu, Beijing Shengbo Xietong Technology Co Ltd, Guangzhou Xinwei Transportation Co Ltd, and Plexus (Xiamen) Co Ltd.

 

Comments are closed.

button