Ilé iṣẹ́ tó ń mójútó ọ̀rọ̀ ibùgbé, yóò ṣàjọṣepọ̀ pẹ̀lú ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àwọn òṣìṣẹ́, Ìrónílágbára
Eyitayọ Fauziat Oyetunji
Ilé iṣẹ́ ìjọba tó ń mójútó ọ̀rọ̀ ibùgbé àti ìdàgbàsókè ìlú ti ṣetán láti jọṣepọ̀ pẹ̀lú ilé ẹ̀kọ́ gíga ti ibùdó àwọn adári fún ìṣàkóso ilé iṣẹ́ láti pèsè ìdánilẹ́kọ̀ọ́ àti Ìrónílágbára fún àwọn òṣìṣẹ́.
Igbesẹ yii waye lati tunbọ jẹ kiawọn eto ile iṣẹ ijọba apapọ naa ati awọn isọri rẹ pọ si, tun oju wọn ṣe nipa fifi imọṣẹ ati ti tun iṣakoso ile iṣe wọn ṣe.

Minisita fun ọ̀rọ̀ ibùgbé àti ìdàgbàsókè ìlú, Arc. Ahmed Musa Dangiwa ni o sọ eyi lasiko ile ekọ naa ṣe abẹwo si.
Minisita wa ṣalaye pataki ipa ti ile ẹkọ naa n ko ninu imọṣẹ ni ile iṣẹ, ṣe igbelarugẹ eto iṣejọba to dara, ti o si tun n ṣafikun ìṣe jakejado isọri.
O tun wa sọ pe orisun to ṣe pataki julọ ni ile iṣẹ ni orisun eniyan, ati pe wọn gbọdọ ro awọn oṣiṣẹ lagbara pẹlu iṣẹ ọwọ to ṣe pataki, ti ọpọlọ, ati ti iwa hihu lati pese iyipada rere ati ilọsiwaju.
Leave a Reply