Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Bola Tinubu ti Yan Mele Kyari ni ìgbà Kejì gẹ́gẹ́ bí ọ̀gá àgbà pátápátá fún ilé iṣé tó ń mójú tó ọ̀rọ̀ Epo rọ̀bì ní Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà NNPCL.
Ààrẹ tún buwọ́lù àwọn alábàáni ṣiṣẹ́ pọ̀ fún ilé iṣé náà
Ààrẹ Yan Alhaji Umar Ida Ajiya, gẹ́gẹ́ bí akápò ati Olóye Pius Akinyelure àti àwọn bẹẹ bẹẹ lọ.
Èyí di mímọ̀ láti ẹnu olubadamoran fún Ààrẹ lori ọ̀rọ̀ tó n lọ Ajuri Ngelale.
Ngelale sọ wí pé ọjọ́ kini oṣù Kejìlá ni iṣé awọn ti won Yan yóò bèrè ní perewu.
Leave a Reply