Take a fresh look at your lifestyle.

Ìyáàfin Soludo rọ àwọn tó nííṣe láti dásí ìfòpin sí ìwà ipá lórí àwọn obìnrin

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 234

Ìyàwó gómìnà ìpínlẹ̀ Anambra, Ìyáàfin Nonye Soludo, ti ṣàlàyé pé gbogbo àwọn tó nííṣe ní láti dìde tí wọ́n bá fẹ́ kí akitiyan láti fòpin sí ìwà ipá lórí àwọn obìnrin àti àwọn ọmọ bìnrin so èso rere.

Ìyáàfin Soludo ti o sọ eleyi di mimọ ninu alaye kan ti o fi sita ni Awka, olu ilu naa, lati ṣami Ayajọ Ìfòpin sí Ìwà Ipá Lórí Àwọn Obìnrin Kariaye 2023, sọ pe bi ko ṣe si ohun awọn ti o pọ ati ti ọrọ naa kan gbọngbọn ko jẹ ki ipolongo naa rinlẹ.

Gẹgẹ bi iyaafin Soludo ṣe sọ, bi iwa aburu naa ṣe n gbilẹ si ninu ile, ibi iṣẹ ati ibaraẹnisọrọ lori ayelujara fẹ amojuto.

O wa rọ ijọba lati wa asiko ati ohun elo fun ipese ilana ti yoo daabobo awọn obinrin.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button