Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Gúsù Àríwá fẹnu kò lórí Àgbákalẹ̀ tuntun

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 208

Ìgbìmọ̀ àwọn Gómìnà Gúsù Àríwá ní Nàìjíríà, NEGF, ti túnbọ̀ fẹsẹ̀ ìpinnu rẹ̀ láti fún gbogbo ọmọ ìlú láǹfààní àti láti pèsè ètò ààbò, ìbáraẹniṣepọ̀ àti àkójọpọ̀ ètò ọrọ̀-ajé ní ẹkùn náà lápapọ̀ múlẹ̀, nínú àpèjọ rẹ̀ ẹlẹ́ẹ̀kẹsàn án, ni Yola, ipinlẹ Adamawa

Igbimọ naa fi idunnu rẹ han si igberu agbara ifọwọsowọpọ ati ajọṣepọ laarin awọn ọmọ ẹgbẹ ipinlẹ naa.

O wa tunbọ fẹsẹ iwulo akojọpọ oniruuru ẹkun ati ṣatunṣe pe ki ọmọ ẹgbẹ kọọkan ko mu ọrọ yii lọkunkun dun nipa jijẹ ki awọn ti wọn yan fun  ojuṣe ninu alaṣe siṣẹ wọn.

Igbimọ tun wa ṣalaye pe iyipada oju ọjọ ati ibajẹ Ayika ṣi jẹ ipeninija pataki fun awọn ẹkun keekee.

O wa o fẹnuko lori titunbọ tẹramọ ajọṣepọ pẹlu gbogbo awọn Eto bii Great Green Wall and the Global Initiative of Carbon Credit financing.

Igbimọ naa tun wa dupẹ fun ṣiṣetan ijọba ipinlẹ Bauchi lati ṣe agbatẹru Ipatẹ ọja Gusu Ariwa ti yoo bẹrẹ niọjọ kẹrindin-lọgbọn, oṣu keji si ọjọ kẹta, oṣu kẹta, 2024.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button