Take a fresh look at your lifestyle.

Ìpínlẹ̀ Zamfara Ṣe Àkọsílẹ̀ Àwọn Ọmọ Tótó Ẹgbẹ̀rún Mọ́kànlá Tí Kò Sí Ìtọ́jú Fún Nípa Oúnjẹ

0 187

Ìpínlẹ̀ Zamfara ṣe àkọsílẹ̀ àwọn ọmọ tó lè ní ẹgbẹ̀rún mọ́kànlá tí ó ń kojú àìsàn nípa ṣe oúnjẹ tí kò péye tó, ẹgbẹ́ tí o n mójú tó ọ̀rọ̀ ìtọjú oúnjẹ lo sọ èyí di mímọ̀.

Ọ̀gbẹ́ni Abrahamu Mahama tó jẹ onímọ̀ nípa ètò oúnjẹ tó dára fún àgọ́ ará lo sí èyí ni ọjọ́ ìṣẹgun nígbà tí o ń Já bọ̀ àwọn èsì Iwadi rẹ tí o tí bẹ̀rẹ̀ láti inú oṣù kẹfà ọdún yìí, ni ìpínlẹ̀ mẹta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ìpínlẹ̀ Sokoto, Kastina àti Zamfara.

Ó sọ̀rọ̀ ní bí ìpàdé ọlọjọ kan ti o dálé lórí bi àtúnse yóò ṣe wà lórí oúnjẹ tó péye fún àwon ọmọ Làgbáyé ati ààbò lórí oúnjẹ pẹ̀lú.

Igbákejì Adarí ilé ẹkọ gíga Fásítì Danfodio Sokoto Ọ̀mọ̀wé Lawal Bilbis rọ àwọn a kópa níbi ìpàdé náà nípa akọsilẹ ti o gbọ wí pé kí wọ́n sa ipá wọn láti rí wí pé wọ́n dẹkùn ìdojúkọ yìí..

Bilbis ṣàlàyé wí pé ayi sí àwọn èròjà tó péye tó ninu oúnjẹ ko dára nitori o n fa àisàn gidigidi sára àwọn ọmọdé àti sí àwùjọ lápapò

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button