Take a fresh look at your lifestyle.

Rògbòdìyàn ìpínlẹ̀ Rivers: Gómìnà Fubara dúpẹ́ lọ́wọ́ ààrẹ Tinubu fún dídásí rẹ̀

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 203

Gómìnà pínlẹ̀ Rivers, Siminalayi Fubara ti fi ọpẹ́ rẹ̀ hàn sí ààrẹ Bọla Ahmed Tinubu fúnìdásí àgbànínú rògbòdìyàn olóṣèlú tó wáyé ní ìpínlẹ̀ náà láìpẹ́ yìí.

Ninu alaye kan ti funra rẹ buwọlu ti o si fi sita fun awọn akọroyin ni ọjọ Abamẹta, Port Harcourt, olu ilu naa, Gomina Fubara sọ pe bi aarẹ ṣe fẹnu si ọrọ naa “faaye gba awọn ọna ibaraẹnisọrọ loriṣiriṣi ti yoo mu ipẹtu si laasigbo oloṣelu to n rúú bọ̀”.

O wa dupẹ lọwọ agba ilu naa, ti o tun fẹnu si ọrọ yii lati ri pe ipinlẹ naa pada ni alaafia ati iduroṣinṣin.

Nigba ti o n ṣalaye ohun ti o fa abẹwo rẹ si ibudo igbimọ ni ọjọ Aje, Fubara sọ pe iroyin pe ile ọ̀wọ̀ igbimọ ipinlẹ Rivers jona gba oun lọkan.

Image

Gomina wa n ṣedani loju pe oun si ṣetan lati gba ọna ti yoo mu alaaafia ati irọrun ọlọjọ pipẹ wa.

O wa tunbọ pinnu ifọkansi rẹ lati lo gbogbo awọn akitiyan ati agbekalẹ aarẹ ati awọn ọmọ Naijiria rere si iyanju rogbodiyan naa layanju delẹ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button