Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn tó niíṣe rọ INEC fún ìdìbò gómìnà otitọ ní Bayelsa, Imo, Kogi

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 198

Àwọn tó niíṣe rọ Ìgbìmọ̀ olómìnira tó ń mójútó ètò ìdìbò lórìlẹ̀-èdè (INEC), láti ríi pé ìdìbò gómìnà ọjọ́ kọkànlá, oṣù kọkànlá ní Bayelsa, Imo àti Kogi lọ nírọ̀wọ́ rọsẹ̀, lótìítọ́ àti léyìí tó ṣeé gbàgbọ́.

Wọn sọ eyi di mimọ lasiko ipade ti ẹgbẹ ara ilu ti iyara bo ṣe n lọ pe, ni Abuja fun idibo to n bọ lọna.
Nigba ti o n sọrọ nibi ayẹyẹ naa, Sẹnetọ Sharafadeen Alli, alaga, igbimọ ile asofin lori ọrọ idibo, wa rọ awọn ile-iṣe eleto aabo lati ṣatunṣe lori ilana iṣẹ wọn lati ri pe awọn oṣiṣẹ wọn ko ṣe ojuṣaju lẹnu iṣẹ wọn lasiko idibo.

Alli wa rọ awọn ti yoo dibo lati maa jẹ ki awọn ika oloṣelu lo wọn fun iṣeru ninu idibo naa nitori pe iru iwa irukerudo naa le da gbogbo eto idibo ru.

O wa sọ pe ti awọn ara ilu lo maa ṣẹ, to ba ti di ọrọ idibo, ti o si sọ pe ihuwa si awọn eniyan ṣe pataki pupọ.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button