Ilé ìfowópamọ́ ìdàgbàsókè Áfíríkà (AfDB), Ilé-ìfowópamọ́ ìdàgbàsókè Mùsùlùmí (IDB) àti owó káríayé fún ìdàgbàsókè ètò ọ̀gbìn ti gbé iye owó Bílíọ́nù kan Dọ́là sílẹ̀ láti túnbọ̀ pèsè abala ilé iṣẹ́ ètò ọ̀gbìn pàtàkì ní àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́rìnlé-lógún ní Nàìjíríà.
Eleyi tun jẹ ikore pataki fun erongba idokowo ijọba aarẹ Bọla Tinubu.
Eleyii wa jẹ afikun si iye owo okòó- lé- ní- ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta Miliọnu Dọla ti alajọṣepọ idagbasoke fun ilọsiwaju awọn abala ipese eto ọgbin ati ile-isẹ ni Naijiria kọkọ fun wọn.
Aarẹ ile ifowopamọ idagbasoke AfirikaPresident of African Development Bank Group, Dokita Akinwumi Adesina, sọ eleyii nibi ijumọ sọrọ kariaye ni Norman Borlaug, Ami Ẹyẹ ounjẹ kariaye 2023, ní Des Moines, Iowa, orilẹ-Amẹrika.
Igbakeji aarẹ Kashim Shettima, ti o n kopa ninu apejọ ni iwọna abayọ lori aabo ounjẹ ati ilana to pin soriṣirisi ijọba Tinubu, ti ṣadanilẹkọ pataki ninu ijumọsọrọ to n lọ lọwọ.
Leave a Reply