Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdìbò ìpílẹ̀ Kogi : Gómìnà pinnu ìkópa ọgbọọgba, ìṣojú

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

0 339

Gómìnà Yahaya Bello ti Kogi ti fi ìkópa ọgbọọgba àti ìṣojú da awọn ọmọ egbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC ni ipinlẹ naa loju ninu idibo gomina ọjọ kọkanla, oṣu Belu ti n bọ lọna yii.

Gómìnà Bello ṣe ipinnu yi lasiko ti o n gba Ọgbeni James Faleke  lalejo.

Falake jẹ igbakeji oludije gomina fun ẹgbẹ oṣelu APC ni 2015, tẹlẹ ri  ti o si jẹ alaga ọmọ ile igbimọ Aṣoju fun igbimọ Inawo lọwọ bayii.

Gómìnà wa n fidi ẹ mulẹ pe ninu APC, gbogbo ọmọ ẹgbẹ lo lanfaani lati ko ipa tirẹ ti ẹgbẹ fun.

Ṣiwaju, Faleke, ti o ko awọn olùkówọ̀ọ́ to lagbara dani lọ sibi àpèjọ naa, wa sọ fun gomina pe abẹwo awọn  fihan gbangba pe awọn ti ṣetan lati siṣẹ ati ṣe ipolongo fun aṣeyọri oludije ẹgbẹ naa, Usman Ododo, ninu idibo gomina ọjọ kọkanla, oṣu Belu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button