Take a fresh look at your lifestyle.

Àtìlẹ́yìn Fún Àwọn Ìpínlẹ̀ Kàn Nàìjíríà Lórí Ètò MSMEs

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 386

Lójúnà látí rán àkitiyan àwọn Ìjọba Nàìjíríà látí mú ìlọsíwájú bá ètò-ọ̀rọ̀ àjé àti ṣé ìdásílẹ̀ ìpèsè iṣẹ́, ẹgbẹ́ àwọn alabaṣepọ kàn lórí ètò àwọn ilé iṣẹ́ kerejekereje [MSMEs] kàn, tí gbèrò ànfààní fún àwọn mílíọ̀nù kán lé díẹ̀ [1.3m] àwọn ènìyàn ní ìpínlẹ̀ mẹ́tàdínlógún [17] àti Olú-ìlú, Abuja.

Àwọn ìpínlẹ̀ tí yóò ní ànfààní náà ní Abia, Rivers, Jigawa, Benue, Borno, Lagos, Ekiti, Niger, Sokoto, Enugu, Gombe, Akwa Ibom, Yobe, Ondo, Osun, Bayelsa, Imo àtí FCT.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button