Take a fresh look at your lifestyle.

Àjọ EU Yóò Gbé Òté Kúrò Lórí Àwọn Onísòwò Ọmọ Ilẹ̀ Russia Mẹ́ta

0 91

 

Àjọ European Union kò ní sọ òte tí wọ́n gbé lórí àwọn oníṣòwò mẹ́ta ọmọ orílẹ̀-èdè Russia di ọ̀tun látàrí ogun ilẹ̀ Russia pẹ̀lú Ukraine bí òte ti tẹ́lẹ̀ ti ń tẹnu bọpo ní ọ̀sẹ̀ yí.

Orúkọ àwọn mẹ́tẹ̀ẹ̀ta ni
Grigory Berezkin, Farkhad Akhmedov ati Alexander Shulgin.

Òté tó wà lórí wọn tẹ́lẹ̀ náà yóò dópin ní ọjọ́ karùndínlógún oṣù kẹsàn án, ọdún 2023.

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave A Reply

Your email address will not be published.