Àwọn olùgbé ní Makurdi, ìpínlẹ̀ Benue, Aringbungbun Nàìjíríà, àti àwọn agbègbè rẹ̀ ti wà nínú pákáleke bí omíyalé ṣe ṣẹlẹ̀ ní àwọn apá kan ìlú náà nítorí òjò àrọ̀ọ̀dá tó rọ̀ fún bíi wákàtí méjìlá.
A gbọ pe ojo, eyi ti o bẹrẹ ni deede agogo mẹwaa alẹ ọjọ Aiku ti o si rọọrọ titi di agogo mẹwaa owurọ ọjọ Aje, fa omiyale ni ọpọlọpọ apa ilu.
Awọn agbegbe ti omi ya wọ ni ọja Wurukum, ile-epo NNPC opopona Otukpo, opopona Gboko , awọn apa kan agbegbe Demekpe, ati ikorita SRS loju ọna ile ẹkọ giga Fafiti Ọgbin ati awọn agbegbe miiran.
A tun gbọ pe awọn akẹẹkọ ati olukọni ti ile-ẹkọ giga FafitiIt Joseph Sarwuan Tarka, JOSTUM, ti a mọ si ile-ẹkọ giga Fafiti Ọgbin tẹlẹ, Makurdi, FUAM, ti wọn ti gbaradi lati foju kekere wo ojo naa kan wa nibẹ ni , ni aarọ ọjọ Aje naa ti wọn ko rọna bọsi ile-iwe wọn.
Leave a Reply