Wọ́n ti rọ àwọn ọmọ ogun láti ní ìgboyà, ìfọkànsìn, ìfaragba lẹ́nu iṣẹ́ wọn.
Adari ọmọ ologun 4 Special Forces, Ajagun Hillary Nzan gba imọran yii nigba ti o n ba awọn ikọ pataki 167 Special Forces Battalion, sọrọ ni ibugbe awọn ọmọ ologun ti Muhammadu Buhari , Giri ní Abuja, lasiko iṣẹ abẹwo si awọn ọmọ ogun naa.
Ajagun Nzan wa rọ awọn ọmọ ogun lati ṣe ara wọn lọkan lai ma wo agbegbe ti wọn ti wa, ẹya wọn tabi ẹsin, ologun Naijiria ti dawọn pọ.
Adari ọmọ ologun tun wa gba wọn nimọran pe “ki wọn maa mu imukumu ati ki wọn si ma wu iwa ipanle kankan.”
Aṣoju Adari awọn oṣiṣẹ ọmọ ogun pataki 167, Ajagun Temipre Ezonfade, gba wọle ti o si sọ diẹ fun ninu awọn eto wọn.
Ajagun Temipre ka awọn aṣeyọri ikọ ologun naa.
Leave a Reply