Ìpínlẹ̀ Zamfara ti kìlọ̀ fún àwọn Kọmísọ́nà tuntun méjìdínlógún tí wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn láti se dáradára ju ti àwọn ti ẹ̀yìn wá lọ.
Èyí di mímọ̀ láti ọwọ́ Gómìnà ìpínlẹ̀ náà,
Dauda Lawal ní ìgbà tí wọ́n ń se ìbúra fún wọn ní Gusau.
“E múra sí iṣẹ́ ní ìlọ́po méjì nítorí a o yẹ̀ yín wò nípa iṣẹ́ tẹ́ ṣe”, ó sọ èyí.
Ìbúra fún wọn wáyé láti ọwọ́ adájọ́ àgbà Ìpínlẹ̀ náà, adajọ Kulu Aliyu..
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply