Take a fresh look at your lifestyle.

Calm Down ‘ Orin Rema Gbayì Ju Gbogbo Orin Ilẹ̀ Adúláwọ̀ Tókù Lọ Nínú Ìtàn Amẹ́ríkà

0 305

 

Gbajúmọ̀ akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè yìí,  Divine Ikubor, ti ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́, Rema, tún ti fi ìtàn balẹ̀.

Orin rẹ̀ tí won fẹ́ràn ‘Calm Down ni wọn ńkọ, ti wọ́n n gbọ́ jùlọ nínú orin ilẹ Adúláwọ̀ ni orílẹ̀-èdè Amerika. Orin náà le “CKay’s ‘Love Nwantiti’ “ dànù láti gbadé ògo náà.

Orí òpó orin ẹrọ ayelujara tweeter Amerika lo gbe àtẹ yìí sita ni ọjọ Ẹti.

Méjèèjì ẹ̀yà orin náà kọjá ìlàjì Bílíọ̀nù gbígbọ́ lórí ẹ̀rọ ayélujára Spotify àti YouTube.
Orin náà tún jẹ orin ilẹ̀ Áfíríkà akọkọ tó léwájú àtẹ Rédíò ilẹ̀ Amẹ́ríkà.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button