Take a fresh look at your lifestyle.

Wizkid Se Ayẹyẹ Ọjọ́ Ìbí Ọdún Mẹ́tàlélọ́gbọ̀n

0 261

 

Gbajúgbajà akọrin ọmọ Nàìjíríà tí wọ́n ń pè ni Wizkid fi kún ọjọ́ ìbí rẹ̀ ní ọjọ́ àìkú. Akọrin “More Love, àti Less Ego’ crooner” pé ẹni ọdún Mẹ́tàlélọ́gbọ̀n lókè erùpẹ̀.

 

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ olólùfẹ́ rẹ ló ti gba orí ẹrọ ayélujára lọ làti kiìí, kíi kú oríire.

 

Wizkid jáde takọ takọ nínú orin rẹ̀- “Holla at Your Boy”, tó gbayì ní ọdún 2011. láti igba náà ló ti jẹ́ ọ̀kan lára Olórin tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button