Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé iṣé (NDE) Ṣe Ìdánilékọ̀ọ́ Fún Àwọn Ènìyàn Àádọ́ta Ní Ìpínlẹ̀ Delta Nípa Ohun Ọ̀gbìn.

0 211

Ilé iṣé NDE ni ìpínlẹ̀ Delta tí ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún Àwọn ènìyàn àádọ́ta ni ìpínlẹ̀ náà fún ìmọ̀ tó péye lórí ìdàgbàsókè ohun ọ̀gbìn.

Àgbékalẹ̀ ètò dì mímọ̀ láti ẹnu Adarí àgbà fún àjọ náà, Mallam Abubakar Nuhu Fikpo, o ní ìdánilékọ̀ọ́ yìí y wa fún ìtọ́sọ́nà ati ìtèsíwájú lori ohun ọ̀gbìn.

Nínú àfikún rẹ o ní ètò ìdánilékọ̀ọ́ yìí yóò jẹ kí wọn mọ àwọn ìdojúkọ ti o n ba ohun ọ̀gbìn fíra àti ọnà láti borí rẹ,pẹ̀lú ànfààní láti jẹ ọ̀gá ará wọn nínú iṣé ọ̀gbìn.

Chukwuma tó n ba àwọn Akọ́pa náà sọ̀rọ̀ o ní kí wọn fí ọkàn sí ohun tí wọn bá kọ wọn láti lè mú lò láwùjọ fún ìdàgbàsókè ètò ọ̀gbìn.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button