Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹgbẹ́ Pè Fún Àwọn Onímọ̀ Láti Ṣàkoso Ètò Ọ̀gbìn.

0 252

Ẹgbẹ́ àwọn àgbẹ̀ tí pè Ààrẹ Bola Tinubu láti yan ẹni tó ní ìmọ̀ nípa ètò ọ̀gbìn láti lè ma ṣe àkóso rè fún ìdàgbàsókè lórí ọ̀rọ̀ ètò ọ̀gbìn

Àwọn ọjọgbọn to lè ní ààdọ́rin tó n ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn ohun tó wúlò jùlọ nínú ètò ọ̀gbìn, ni o pé ìpè náà nígbà tí wọn bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ ní ìlú Abuja.

Alahji Ali Baba aláṣẹ ilé iṣé Pastoral and Livestock Feed ti ṣe agbẹnusọ fún náà ni ẹgbẹ́ ní yíyan onímọ̀ ati ẹni tó mọ nípa ètò ọ̀gbìn yóò mú ìdàgbàsókè kiakia ba Orílẹ̀-èdè.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button