Take a fresh look at your lifestyle.

Olùkọrin Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Niniola Gbé Fidio Orin Tuntun Kan Jáde

0 275

 

Olùkọrin Afrobeats Ọmọ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Niniola ti gbé Fidio orin tuntun tó pe àkọ́lé rẹ̀ ní “Gbogbo Ojú Lára Mi” tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣe jáde.

 

“Gbogbo Oju Lára Mi” jẹ́ èkejì tó gbé jáde ní ọdún yìí. Àwọn Caltonic àti Niphkeys ni atọ́nà rẹ̀.

Orin náà ni wọ́n kéde pé yóò jade láìpẹ́

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button