Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn Ẹgbẹ́ Kàn Tí Rọ́ Àwọn Àlẹ́nu-lọ́rọ́ Lórí Ètò Ìlera Tó Péye

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 344

Ìgbìmọ̀ Ìmọ-iṣẹ́ Iṣoogun tí Nàìjíríà (Medical Laboratory Science Council of Nigeria MLSCN) tí kepè àwọn alẹ́nu-lọ̀rọ̀ látí fọwọsowọpọ pẹ̀lú Àjọ náà láti lè ṣé itọju àti ìlera tó tọ́.

Dókítà Tosan Erhabor, Alákóso ìgbìmọ̀ to pé ìpè yìí ní Abuja sọ pé àwọn iṣẹ́ náà yóò wà ní ibamu pẹlu awọn iṣẹ ti o dara julọ lagbaye gẹ́gẹ́ bí a tí pinnu ní Òfin 11, 2003.

Gẹ́gẹ́ bi o tí sọ, èyí yóò jẹ́ ọnà àbáyọ́ tó dára jùlọ láti lè jẹ́ kí àwọn ènìyàn ní Ìgbàgbọ àti iṣé ìgbìmọ̀ alaṣẹ orílẹ̀-èdè yìí

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button