Take a fresh look at your lifestyle.

Olùwá-oúnjẹ India Kí Olùwá-oúnjẹ Nàìjíríà, Hilda Baci Kú Oríire

0 211

Olùwa-oúnjẹ India, Lata Tondon ti kí Olùwa-oúnjẹ Nàìjíríà, Hilda Effiong Bassey, tí wọ́n mọ̀ sí Hilda Baci, ku oríire lẹ́yìn tí ó ti fi àjùlọ hàn. Ó fi ìtàn balẹ̀ bí Olùwá-oúnjẹ tó yára, tó pẹ́ jùlọ ní àgbáyé.

Hilda Baci ti kọ orúkọ rẹ̀ sínú ìwé ìtàn ti
Guinness ní ọjọ́ Ìṣẹ́gun gẹ́gẹ́ bí ẹnìkan ṣoṣo, Olùwá-oúnjẹ tó yára, tó pẹ́ julo ní àgbáyé.
Ó lo Wákàtí mẹ́tàlélláàdọ̀rún àti ìsẹ́jú mọ́kànlá, yàtọ̀ sí ọgọ́rún wákàtí tó ti kọ́kọ́ dé.

Tondon to ti gba irú àmì ẹ̀yẹ bẹ́ẹ̀ rí ki kú oríire. Ó kọ lọri ẹ̀rọ ayélujára rẹ pé,
” Inú mi dùn fún Hilda Baci àti ọmọ Naijiria, inú mi dun fún gbogbo yín, inú mi dùn gidigidi fún Hilda!”
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button