Take a fresh look at your lifestyle.

Akọrin Ọmọ Nàìjíríà, Tems TaYọ Kọjá Rihanna Àti Beyonce Nínú Àte US Billboard Tuntun

0 233

Akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè ti fi ìtàn balẹ̀ nínú àtẹ US Billboard ti orin ju Olùkọrin Obinrin ti orílẹ-èdè Amerika, ògbóǹtarìgì bíi Rihanna àti Beyonce.

Ọ̀gbóǹtarìgì ọmọ Nàìjíríà tó ti gba àmì ẹ̀yẹ orin ni ìgbà kan ri ti lù aluyọ̀ ní àkọ́lé orin rẹ̀ “Free Mind’” tí ó wá jẹ́ kó jẹ́ àkọ́kọ́ obìnrin tó má lékè lórí àtẹ orí afẹ́fẹ́ Billboard R&B/Hip-Hop ti Olórin nínú ìtàn.

Orin Tems dúró gbári sí ipò kínní lórí àtẹ ní ọ̀ṣẹ̀ yìí tó jẹ Ọ̀sẹ̀ mẹtàdínlógún ni àpapọ̀ ní òkè téńté tó sì fi itan balẹ̀ bi olórin obìnrin tó máa ṣe bẹ́ẹ̀.

 

Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button