Take a fresh look at your lifestyle.

Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Ń Pépé Fún Ìtùsílẹ̀ Àwọn Ìnáwó Ọkọ Òfurufú

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 484

Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí rawọ ẹ̀bẹ̀ sí awọn ilé-iṣẹ́ ọkọ Òfurufú káríayé látí má ṣé daṣẹ́ dúró làkókò tí àwọn àkitiyan ń lọ́ lọwọ́ láti yanjú àwọn ìdíwọ́ tó ń ṣókùnfá ìdìnà ìnáwó àwọn ọkọ òfurufú lórílẹ̀-èdè yìí.

Àwọn aṣòfin tún rọ́ Ààrẹ Muhammadu Buhari láti pàṣẹ fún ilé ìfówópámọ́ àpapọ̀ (Central Bank of Nigeria) látí sàn owó fún àwọn ọkọ Òfurufú tó kàn.

Àwọn Aṣòfin náà ṣé àkíyèsí pé fún ọdún kàn, Nàìjíríà tí jẹ́ orílẹ̀-èdè tó dínà mọ́ ìyè òwò tí ọkọ Òfurufú tó pojú ní àgbáyé.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button