Ààrẹ Nana Akufo-Addo tí Orílẹ̀-èdè Ghana ní á n’ìrètí látí ṣé Alága ìgbéjáde àtí ìfilọ́lẹ̀ àwọn ìwé túntún méjì kàn lórí àwọn ipá tí Aare Muhammadu Buhari kó lórí ìdàgbàsókè Orílẹ̀-èdè ní ọjọ́ Ẹtì, ọjọ kokandinlogun 19 Oṣù Kàrún ùn, ní Ilé-iṣẹ́ Àpéjọ Ilé-ìgbìmọ̀ àpapọ̀ (State House), Abuja.
Gẹ́gẹ́ bí Ambasado Babagana Kingibe tó jẹ́ Alága Ìgbìmọ̀ tó n ṣètò fún ayẹyẹ náà ṣé sọ, àwọn àlejò pàtàkì mìíràn tí á ń retí níbí ìgbéjáde ìwé náà ní Bola Tinubu, Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n yan, àtí ìgbákejì rẹ̀ Kashim Shettima.
Tún kà nípa: Ààrẹ Buhari Padà Sí Ìlú Abuja.
Àwọn ìwé fún ìgbéjáde tí gbogbo ènìyàn ní: “ÀTÚNṢE ÌPÍNLẸ̀: BÍ MUHAMMADU BUHARI ṢÉ GBÌYÀNJÚ LÁTI TÚN NÀÌJÍRÍÀ RỌ́ SÍ DÁRA DÁRA” látí ọwọ́ Anthony Goldman, Akọ̀ròyìn tẹ̀lẹ̀ rí àti Olóòtú àtijọ́ tí Africa Financial Times tí London; àtí “ÌFILỌ́LẸ̀ TÍ MUHAMMADU BUHARI” nípasẹ̀ Senator Abu Ibrahim.
Leave a Reply