Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari Padà Sí Ìlú Abuja.

0 174

Ààrẹ Muhammadu Buhari tí padà sí ìlú Abuja láti Orílẹ̀-èdè London, níbi tí o wà fún ọjọ́ Mẹ́tàlà gbáko.

Ààrẹ Buhari ti o padà ni alè ọjọ́ ìṣẹgun ni olórí àwọn Òṣìṣẹ́ Ibrahim Gambari àti Mínísítà fún Ìpínlẹ̀ Abuja Mohammed Bello ki Káàbò

Ààrẹ Buhari rin ìrìn àjò lọ sí ìlú London ni ọjọ́ kẹta oṣù karún-ún fún ayẹyẹ ìgbadẹ́ Ọba Charles Kẹta ti o wáyé ní Ọjọ́ kẹfà ọjọ́ Àbámẹ́ta oṣù karún-ún.

Lẹ́yìn ìgbà náà ni Aare simi fún ọ̀sẹ̀ kàn láti fi àǹfààní náà  rí dókítà rẹ nipa ẹyìn.

Wọn n retí Ààrẹ láti darí ìpàdé àwọn ìgbìmọ̀ ni ọlá ni ilu Abuja.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button