Take a fresh look at your lifestyle.

Mínísítà Ilẹ̀ Òkèèrè Kí Àwọn Aṣojú Angola, Britain Àtí America Kú Ìṣẹ́ Takuntakun

Ọlálékan Ọ̀rẹ́núgà

0 240

Mínísítà fún Ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèèrè tí Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Geoffrey Onyeama tí ṣé ètò ìdágbéré sí aṣojú Angolan tí yóò fí ipò sílẹ̀, Eustaquio Quibato, Kọmisọna gíga tí Ìlú Gẹ̀ẹ́sì (British High Commissioner) Catriona Laing àtí aṣojú America, Mary Beth.

Tún kà nípa:Ìjọ̀ba Orílẹ̀-èdè Congo Rọ̀ Ààrẹ Macron Láti Fòfin Dé Rwanda Lórí Ìwà Ipaniyan M23

Èyí ló ṣẹ̀lẹ̀ ní Àárọ̀ ọjọ́ Ajé, Ogúnjọ́ Oṣù Kẹta, Ọdún 2023.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button