Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdìbò Ti bẹ̀rẹ̀ ní ibùdó ìbò Igbákejì Ààrẹ Osinbajo Ní Ikenne, Ìpínlẹ̀ Ogun

0 249

Idibo ti bẹrẹ ni Ibudo idibo 014, Egunrege, Ikenne Wọọdu kinni, Ijọba ibilẹ Ikenne, Ipinlẹ Ogun fún ibo Gomina àti Aṣofin ipinlẹ.

Ni deede aago mẹjọ aarọ, oluranlọwọ alaga ajọ eleto idibo ti orilẹ-ede Naijiria, INEC, kede ibẹrẹ idibo naa.

Igbakeji Aare Osinbajo ati iyawo rẹ, Dolapo, ni yoo dibo ni ẹka ibo kẹrinla.

Ààbò to peye wa ni ẹka idibo agbegbe naa labẹ iṣọ ọlọọpa kan àti oṣiṣẹ binrin Aabo Ilu lorilẹde Naijiria, (NSCDC).

 

 

George Oláyinká Akíntọ́lá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button