Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdìbò Ńlọ lọ́wọ́ Báyìí Ní Ìpínlẹ̀ Nasarawa.

0 293

Àyẹ̀wò orúkọ àti ìdìbò nlọ lówó báyìí ni Akwanga ni bi eto idibo yiyan Gómìnà àti asojú ilé ìgbìmọ̀ aṣofin ìpínlẹ̀ ni ipinlẹ Nassarawa.

 

Òṣìṣẹ́ àjọ elẹ́tò ìdìbò bẹ̀rẹ̀ ni dédé agọ mẹ̀san kọja isẹju mẹ́jo òwúrọ̀

 

Àwọn ènìyàn kò fi bẹ́ẹ̀ jade láti dìbò agbègbè tuntun fún ìdìbò tó péye awọn òṣìṣẹ́ elẹ́tò aláàbò sí wá ni agbègbè náà láti rí wí pé òhun gbogbo lọ ni irọrun.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button