Take a fresh look at your lifestyle.

Ìdìbò Gómìnà: Àyẹ̀wò Orukọ Àwọn Olùdìbò Yóò Bẹ̀rẹ̀ Ni Ìpínlẹ̀ Borno.

0 223

Àwọn òṣìṣẹ́ elẹ́tò ìdìbò ti gbaradì fún àyẹ̀wò ati ìdìbò yíyan Gómìnà àti asojú ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ní Maiduguri ni ìpínlẹ̀ Borno.

 

Ní agbègbè ilé ìjọba tó wà ní ìpínlẹ̀ Borno àwọn elẹ́tò ìdìbò ti dé si bẹ ni agọ méje ku isẹju mẹẹdọgbọn àárọ̀ pẹ̀lú àwọn èròjà ìdìbò.

 

Àwọn tó forúkọ sílẹ̀ ní agbègbè ilé ìjọba jẹ́ 1241, agbègbè náà si wá ní àlàáfíà.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button