Ní Ibùdó Ìdìbò Kẹjo (008), Government Trade Centre, Ìjọba ibilẹ Ebonyi, àwọn òṣìṣẹ́ elétò ìdìbò àti ti àjọ INEC ti gúnlẹ̀ sí ibẹ̀. Ní ibi ibùdó ìbò yìí, ìṣòro ọ̀dà ti wọn o fi tẹ ìka àtànpàkò láti di ìbò ni o ń báwon fínra.
Àjọ INEC ti bẹ̀rẹ̀ sí ní lo àwòrán tó wà lórí ẹ̀rọ BVAS látàrí ìṣòro yìí láti lè mú kí iṣẹ́ wọn tẹ̀ síwájú.
Tèmítọ́pẹ́ Òbísẹ̀san
Leave a Reply