Take a fresh look at your lifestyle.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Borno, Ọ̀jọ̀gbọ́n Babagana ti dìbò

0 322

Gomina ipinlẹ Borno, Ojogbon Babagana Umara Zulum ti dibo rẹ ni ẹka ibo ni ilu abinibi rẹ ni Mafa, Ajari 006, ìpín B.

 

Nọmba awọn oludibo ti o forukọsilẹ jẹ mẹfalelẹgbẹrin lapapọ ní ẹka idibo naa.

O gboriyin fun awon araalu fun bi wọn se jade lati dibo wọn, o si rọ wọn lati wa ni isokan ati alaafia jakejado.

 

Mafa ni olu ileeṣẹ ijọba ibilẹ Mafa ni Borno, nkan bii 35km si Maiduguri.

Ile Akede Naijiria, Voice of Nigeria lo jábò pe àwọn oṣiṣẹ aabo wa ni ọpọlọpọ awọn agbegbe ibo lati rii daju pe eto idibo naa waye lai si wahala kankan.

 

 

George Ọláyinká Akíntọ́lá.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button