Take a fresh look at your lifestyle.

Ètò Ìdìbò Ti Bẹ̀rẹ̀ Ní Pẹrẹwu Ní Ìpínlẹ̀ Jigawa

0 217

Ìdìbò láti yan Gómìnà àti àwọn ọmọ Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Ìpínlẹ̀ ti bẹ̀rẹ̀ ní ìlú Dutse, Ìpínlẹ̀ Jigawa.

 

Ní ibùdó ìdìbò ẹlẹ́ẹ̀kẹrìnlélógún, ilé-ìwé alákọ̀bẹ́rẹ̀ẹ̀ ti (Mobile), ètò ìdìbò ti bẹ̀rẹ̀ láti aago mẹ́jọ kọjá díẹ̀ lówùrọ́ọ̀ ọjọ Àbámẹ́ta.

 

Nígbà tí àjọ elétò ìdìbò ti gbáradì láti aago méje àbọ̀ òwúrọ̀, àwọn ẹ̀sọ́ aláàbò ti pésẹ̀ wámú-wámú fún ìkẹ́ṣejárí ètò ìdìbò àti fún ààbò tí ó péye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

button