Ni agbegbe Umuahia ni ìpínlẹ̀ Abia níbi tí àwọn àjọ elẹ́tò ìdìbò kalẹ si fún ìdìbò yíyan Gómìnà àti asojú ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ ní àyẹ̀wò ìdìbò ti bẹ̀rẹ̀.
Ilé Akéde Nàíjíríà Voice of Nigeria ṣe ìbẹ̀wò sí àwọn agbègbè ìdìbò tó tó ogun ni wọ̀ọ́dù mẹta ni Umuahia nibi ti àwọn àjọ elẹ́tò bẹ̀rẹ̀ ìdìbò ni dédé agọ mẹ̀san òwúrọ̀.

Ni àwọn agbègbè bi mẹta kan ni ko sí tabili ti eléyìí sí fa àkóbá fún ìdìbò lati wáyé
Oníròyìn Ilé Akéde Nàíjíríà Voice of Nigeria sọ wí pé ìdìbò nlọ lọ́wọ́ ní àwọn agbègbè mẹ́tàdìnlọ́gbọ̀n láàrin ìpínlẹ̀ náà báyìí ti awon elẹ́tò ààbò sí wa ni ìkàlẹ̀ pẹ̀lú .
Leave a Reply