Àjọ INEC tó ń ṣe àkójọpọ̀ èsì ìbò lórílèdè Nàíjíríà sún ìjókòó wọn di aago mẹ́fà ìrọ̀lẹ́.
Àjọ elétò ìdìbò Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà (INEC), ti sún àkójọpọ̀ èsì ìdìbò Ààrẹ ọdún 2023 di aago mẹ́fà ìrọ̀lẹ́ ní ọjọ́ Àìkú.

Alága Àjọ elétò ìdìbò Orílẹ̀-èdè Nàíjíríà (INEC), Ọ̀jọ̀gbọ́n Mahmood Yakubu, ti sọ ní ọjọ́ sátidé pe àkójọpọ̀ ìbò yóò bẹ̀rẹ̀ ní ọ̀sán ọjọ́ Àìkú.

Ju gbogbo rẹ̀ lọ, nínú ìfọ̀rọ̀wérọ̀ kan láti kéde àkójọpọ̀ náà ní ọjọ́ Àìkú, Yakubu sọ pé yóò bẹ̀rẹ̀ ní aago mẹ́fà ìrọ̀lẹ́.

Ìdìbò aarẹ ọdún 2023 yóò lagbara gan laarin awọn oludije ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressive Congress, APC, Bola Ahmed Tinubu, ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party, PDP, oludije, Atiku Abubakar àti ẹgbẹ́ òṣèlú Labour Party LP, Peter Obi.
Ọláyinká Akíntọ́lá.
Leave a Reply